prompt stringlengths 3 7.88k | completion stringlengths 1 7.81k |
|---|---|
Sọ fúnmi nípa Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. | Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ Ìpínlẹ̀ tí ó wà ní àárín gbùngbùn apá Ìwọ̀-Oòrùn Gúúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Ìlú Òṣogbo. Ó ní ibodè ní àríwá mọ́ Ìpínlẹ̀ Kwara, ní ìlà-oòrùn díẹ̀ mọ́ Ìpínlẹ̀ Èkìtì àti díẹ̀ mọ́ Ìpínlẹ̀ Oǹdó, ní gúúsù mọ́ Ìpínlẹ̀ Ògùn àt... |
Ijọba ti fi katakata yanju iyooku ile to wo l’Ebute-Mẹtta, wọn ni ki lanlọọdu ile naa yọju kia | Laika ti pe ayẹwo ṣi n lọ lori ohun to fa iṣẹlẹ ile alaja mẹta kan to ṣadeede wo lulẹ lapa kan lọsan-anSatide to kọja yii si, ijọba ti gbe katakata lọ sibi iṣẹlẹ ọhun, wọn si ti wo gbogbo awoku ile naa to wa lori iduro palẹ, bẹẹ ni wọn kede pe ki lanlọọdu ati abanikọle (difẹlọpa) to kọle naa yọju lati dahun awọn ibeere... |
Fulani darandaran, fijilante ati ikọ Amọtẹkun kọ lu ara wọn niluu Kọmu | Ilu Kọmu, nijọba ibilẹ Itẹsiwaju, nipinlẹ Ọyọ, ni wahala ti waye l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ to kọja, lakooko ti ikọ Amọtẹkun fẹẹ gba awọn ohun ija oloro tawọn Fulani darandaran kan lagbegbe ọhun saaba maa n ko kiri, eyi ti wọn ni wọn ko gbọdọ wọnu ọja ilu naa pẹlu awọn nnkan ija bẹẹ. Gegẹ bi ẹni tiṣẹlẹ naa ṣoju ẹ ṣe ṣalaye ... |
Big Brother Naija: Ọlamilekan lo ko owo rẹpẹtẹ lọọ ba mama ẹ nile | Orukọ a maa ro ni o, bẹẹ gan-an lọrọ Ọlamilekan Agbeleshe ṣe ri nigba ti wọn kede pe oun lo jawe olubori ninu idije eto kan to waye lori DSTV, ti wọn pe ni Big Brother Naija lockdown apa karun-un. Miliọnu marundinlaaadorun-un (85m) ni ọdọmọkunrin ti ko ju ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn, to tun jẹ ọmọ ipinlẹ Eko, yii jẹ. Ileew... |
Eefin jẹnẹretọ pa awọn olorin taka-sufee meji sibi ti wọn ti lọọ kọrin l’Agbado | Niṣe lọrọ ba ibomi-in yọ fawọn onkọrin taka-sufee meji kan, Lawal Ajibawo, ẹni ọdun mẹtadinlogoji, ati Sunday Akhigbe, ọmọ ọdun mejila pere, pẹlu bi wọn ṣe fẹsẹ ara wọn rin lọ sibi ti wọn ti fẹẹ kọrin sinu awo lalẹ Ọjọbọ, Tọsidee, to kọja, ṣugbọn to jẹ oku awọn mejeeji ni wọn gbe jade ninu ile orin ọhun laaarọ ọjọ keji... |
Aṣofin PDP gboṣuba fun Oyetọla lori sisan owo-oṣu tuntun fawọn oṣiṣẹ l’Ọṣun | Aṣofin to n ṣoju awọn eeyan Obokun/Oriade nile-igbimọ aṣofin apapọ orileede yii, Ọnarebu Oluwọle Ọkẹ, ti sọ pe Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, yẹ lẹni teeyan gbọdọ gboriyin fun lori bo ṣe fọwọ si sisan owo-oṣu tuntun fun awọn oṣiṣẹ ijọba. Ninu atẹjade kan ti Wọle Ọkẹ fi sita lọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, lo t... |
Agolo tomato l’Okorie fẹẹ fi gbe egoogi oloro lọ siluu oyinbo tọwọ fi tẹ ẹ l’Ekoo | Wọn ti ni ki gbogbo ẹni to ba mọ nnkan i fi pamọ maa ranti ẹni to mọ nnkan i wa lawakan, eyi lo difa fun ọkunrin oniṣowo egboogi oloro to filu Eko ṣe ibugbe yii, Eze Celestine Okorie, tomato alagolo nla lo loun fẹẹ ko lọ fawọn eeyan oun kan niluu eebo, aṣe irọ lo n pọn lewe, egboogi oloro ni jagunlabi rọ sinu ẹ, lọwọ b... |
Muyiwa Adejọbi di agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa Eko | Ọga ọlopaa patapata, Muhammed Adam, ti yan Ọmọọba Muyiwa Adejobi gẹgẹ bii agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko. Eyi ni pe gbogbo ohun to ba ṣẹlẹ lọdọ awọn ọlọpaa, tabi laarin awọn araalu pẹlu ọlọpaa, lẹnu Adejọbi lẹ o ti gbọ ọ. Adejọbi ki i ṣe ọgbẹri nidii ise igbẹnusọ yii, nitori iṣẹ to n ṣe fawọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun lati... |
Ẹgbẹ alatako ni oṣelu ni Akeredolu fẹẹ fi owo ileewe fasiti to din ku l’Ondo ṣe | Oriṣiiriṣii ọrọ lawọn ẹgbẹ alatako n sọ si Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, lori bo ṣe kede adinku si owo ileewe ti wọn n san ni Fasiti Adekunle Ajasin to wa l’Akungba-Akoko. Ko ju bii ọdun kan pere ti wọn dibo yan gomina ọhun lo kede afikun owo ile-iwe ti wọn n san ni fasiti naa lati ẹgbẹrun marundinlogoji naira ... |
Nitori Sunday lgboho, awọn Fulani sa lọ sodọ Makinde | Nitori bi akinkanju ọmọ Yorùbá nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ, ẹni tí gbogbo eeyan mọ si Sunday Igboho, ṣe fun wọn ni gbèdéke ọjọ meje pere lati fi ipinlẹ Ọyọ silẹ, awọn Fulani ti rawọ ẹgbẹ si ijọba ipinlẹ Ọjọ lati gba awọn lọwọ Igboho. Seriki Fulani, nipinlẹ Ọyọ, Saliu Abdul-Kadiri, lo rawọ ẹbẹ yii lorukọ awọn Fulani ẹgbẹ ... |
A maa wọ ẹnikẹni to ba tun sọ isọkusọ nipa mọlẹbi wa lọ sile-ẹjọ – Idile Ọrangun Ila | Idile ọlọmọọba Arutu Oluokun, nibi ti Ọrangun tilu Ila, Ọba Wahab Oyedọtun, ti wa, ti leri pe ẹnikẹni to ba tun sọ isọkusọ nipa mọlẹbi naa nibikibi yoo foju bale-ẹjọ. Ninu atẹjade kan ti olori ile naa, Ọmọọba Ọlayiwọla Abimbọla, fun ALAROYE lopin ọsẹ to kọja ni baba naa ti sọ pe oun to ṣẹlẹ lọdun to ti pẹ sẹyin lawọn k... |
APC lo yege ibo alaga kansu ni gbogbo ijọba ibilẹ ogun nipinlẹ Ogun | Ẹyọ kan ṣoṣo bayii ko ṣẹku ninu ijọba ibilẹ Ogun to wa nipinlẹ Ogun, eyi ti ẹgbẹ oṣelu APC ko mu ninu ibo ijọba ibilẹ ti wọn di lọjọ Satide to kọja yii, iyẹn fun ti awọn alaga ijọba ibilẹ. Gbogbo awọn to dupo ṣiamaanu wọn lo wọle pata. Aarọ kutu ọjọ Sannde ti i ṣe ọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu keje, ni Alaga ajọ eleto idibo Ogun... |
Ẹ wo Baalẹ to n ba ọmọ bibi inu ẹ sun l’Owode-Yewa | Lẹyin ọdun kẹrin to ti n ba ọmọ bibi inu ẹ to jẹ obinrin sun, aṣiri Baalẹ Oose Agbẹdu Ajibawo, l’Owode Yewa, Rasheed Sholabi, ti tu bayii, awọn ọlọpaa ti mu un. Ọmọ rẹ ti wọn lo n ba sun naa lo lọọ fẹjọ sun ni teṣan ọlọpaa Owode-Ẹgbado. O ṣalaye fun wọn pe ọmọ ọdun mọkanla pere loun wa ti baba oun ti n ba oun lo pọ, ọm... |
Mọto ti wọn ni ki Kazeem fọ ni Festac lo n gbe sa lọ tọwọ fi ba a n’Idoroko | Bi Kazeem Ọlanrewaju tẹ ẹ n wo yii ṣe n fi mọto sare, ti mọto ọhun ko si tun ni nọmba idanimọ kankan lo fu awọn ọlọpaa lara lagbegbe Idiroko, lọjọ kẹfa, oṣu kẹrin, ọdun 2021 yii. Bi wọn ṣe da a duro to tun fere ge e si tun jẹ idi kan ti wọn fi mọ pe ọwọ rẹ ko mọ rara. Mọto Venza ni Kazeem n wa lọjọ naa gẹgẹ bi DSP Abim... |
Bi ẹnikẹni ba kọlu yin, ẹyin naa ẹ kọlu wọn – Ọga ọlọpaa patapata | Nitori bi awọn janduku kan ṣe pa awọn ọlọpaa nipakupa lasiko rogbodiyan SARS, Ọga ọlọpaa orilẹ-ede yii, Mohammed Adamu, ti paṣẹ fawọn agbofinro pe ki awọn naa kọlu wọn lati daabo bo ara wọn lọwọ awọn tọọgi to ba doju ija kọ wọn. Adamu sọrọ yii nigba to lọọ ṣabẹwo lori eto aabo kaakiri ilu Abuja. O ni, “Araalu ni ẹyin ọ... |
Abiọdun ati Ọpẹyẹmi fibọn gba ọkada ni Sango, nibi ti wọn ti n sa lọ lọwọ ọlọpaa ti tẹ wọn | Ni nnkan bii aago mẹjọ alẹ ọjọ kẹwaa, oṣu karun-un yii, ni olobo ta awọn ọlọpaa teṣan Sango, nipinlẹ Ogun, pe awọn gende meji yii, Abiọdun Ogundele; ẹni ọdun mẹtalelogun, ati Ọpẹyẹmi Ọlatubọsun, ẹni ọdun mejilelogun, fibọn gba ọkada lọwọ ọlọkada kan nibudokọ Jọju, wọn si ti fẹsẹ fẹ ẹ. Ṣugbọn nibi ti wọn ti n sa lọ naa ... |
Ijọba o gbọdọ fun ẹnikẹni labẹrẹ ajẹsara Korona ni tipatipa-Ile-ẹjọ lo sọ bẹẹ | Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Port-Harcourt, nipinlẹ Rivers, ti sọ pe ọrọ gbigba abẹrẹ ajẹsara arun Koronafairọọsi ni Naijiria, ẹni to ba fẹ, to si nifẹẹ si gbigba abẹrẹ naa lo le lọọ gba a, ki i ṣe ọrọ tulaasi, bẹẹ nijọba o gbọdọ fipa fun ẹnikẹni labẹrẹ ọhun. Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee yii, nile-ẹjọ naa gbe aṣẹ yii ... |
Egbé àwon tó ń kópa pàtàkì nínú ètò ìsèlú láyé àtijó ni | ògbóni |
Wọn ti le ọlọpaa mẹta to fipa gbowo lọwọ akẹkọọ LASU lẹnu iṣẹ | Awọn ọlọpaa mẹta nni,Inspẹkitọ Sunday John, Sajẹnti Jimọh Asimiya ati Sajẹnti Solomon Adedapọ ti wọn fipa gbowo lọwọ akẹkọọ LASU, Sheriff Adedigba, l’Owode-Ẹgba, ti padanu iṣẹ wọn bayii, ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti gbaṣẹ lọwọ wọn. Ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, ni aṣiri awọn ọlọpaa naa tu, lẹyin ti wọn fipa gba ẹgbẹrun lọ... |
Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun pa eeyan mẹta l’Oṣogbo | Titi di asiko ti a n koroyin yii jọ, paroparo ni agbegbe Kọlawọle, Orita Alie, ati Ọbalende, niluu Oṣogbo, da latari bi awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ṣe ṣọṣẹ nibẹ laaarọ ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii. A gbọ pe awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti wọn n pe ni Aiye ni wọn n ṣoro kaakiri bii agbọn, ti wọn si n dọdẹ awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti wọn n... |
Adajọ ti ni ki wọn lọọ yẹgi fun Ọlanrewaju ati Kazeem ti wọn jale l’Ekiti | Ile-ẹjọ giga ipinlẹ Ekiti to fikalẹ siluu Ado-Ekiti, ti dajọ iku fawọn meji kan, Ọkẹ Ọlanrewaju ati Ọlanbiwọnnu Kazeem, lẹyin ti wọn jẹbi ẹsun igbimọ-pọ ṣiṣẹ ibi ati idigunjale. Onidaajọ Lekan Ogunmoye lo gbe idajọ naa kalẹ lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii. Akọsilẹ kootu naa ṣalaye pe ogunjọ, oṣu keje, ọdun 2016, ni Ọkẹ to jẹ ... |
Kí ni a ń pe oṣù àkọ̀kọ̀ ní Yorùbá? | Oṣù Bẹẹrẹ. |
Iwa buruku ti Ọbasanjọ ti hu sẹyin lo n yọ ọ lẹnu o – Ladọja lo sọ bẹẹ | Wahala buruku lo n ṣẹlẹ laarin Sẹnetọ Rashidi Ladọja, gomina ipinlẹ Ọyọ, tẹlẹ lori bi Ọbasanjọ ṣe sọ pe iwa aimoore ẹ lo jẹ ki wọn yọ ọ nipo lọdun 2005 Ana Furaidee, ọjọ Ẹti ni Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ sọrọ kan, ohun to si sọ ni pe iwa alaimoore ti Rashidi Ladọja hu sawọn eeyan meji kan ti wọn ran an lọwọ to fi di gomin... |
Ọmọ Akunyili ti wọn pa ni: Emi ati baba mi ṣi sọrọ lo ku ọla to maa ku | Ọrọ idaro to n ti ẹnu Abilekọ Chidiogo Akunyili-Parr, ọkan lara awọn ọmọ oloogbe, Dokita Chike Akunyili, jade, lasiko yii fi bi ibanujẹ iku baba wọn to jade laye lojiji ṣe ka a lara to han. Dokita Akunyili, ọkọ Ọga agba ajọ NAFDAC tẹlẹ nilẹ wa, Ọjọgbọn Dora Akunyili, lawọn kan ṣeku pa lọjọ Iṣẹgun, Tusidee ọsẹ yii, lagb... |
Oyetọla fopin si konilegbele l’Ọṣun | Nitori bi awọn eeyan ṣe tẹle ofin konilegbele oni wakati mẹrinlelogun ti gomina Ọṣun, Isiaka Oyetọla paṣẹ rẹ, ijọba ti sọ pe awọn ti fagi le konilegbele nipinlẹ naa, wọn ni awọn araalu le maa jade sita. Oyetọla dupe lọwọ awọn araalu fun ifarada ati agbọye ti won ni pẹlu ijọba, bẹẹ lo gboriyin fun awọn ọdọ pẹlu bi wọn ṣ... |
Arun korona kọlu olori Amẹrika ati iyawo ẹ | Bi eto idibo ilẹ America ṣe n sunmọ, ti ipolongo ibo n lọ kikankikan, Aarẹ orilẹ-ede naa, Donald Trump, ti lugbadi arun koronafairọọsi pẹlu iyawo ẹ bayii o. Loni-in, Fraidee, ọjọ Ẹti ni iroyin ọhun jade. Ohun ti dọkita ẹ si sọ ni pe, ki i ṣe pe arun koronafairọọsi naa ti da a dubulẹ, Trump ṣi le maa ba iṣẹ ẹ lọ bo ti ṣ... |
Adajọ ti ju Muritala sẹwọn l’Oṣogbo, apo igbo meji ni wọn ka mọ ọn lọwọ | Ọkunrin ẹni ọdun mejilelọgbọn kan, Babarinde Muritala, ladajọ ile-ẹjọ giga tijọba apapọ to wa niluu Oṣogbo ti sọ sẹwọn ọdun kan bayii lori ẹsun pe wọn ka igbo (Indian hemp) mọ ọn lọwọ. Ajọ to n gbogun ti lilo oogun oloro (NDLEA), lo wọ Muritala lọ si kootu. Agbẹnusọ fun ajọ naa, Ogaga Azuigo, sọ fun kootu pe baagi igbo... |
O le jẹ awọn janduku lo wọ aṣọ ṣọja, ti wọn yinbọn paayan ni Lẹkki-Adajọ agba ilẹ wa | Minisita fun eto idajọ nile wa, Abubakar Malami, ti sọ pe o ṣee ṣe ko jẹ awọn janduku ni wọn ko aṣọ awọn ṣọja wọ, ti wọn si lọọ yinbọn lu awọn ọdọ to n ṣewọde ta ko SARS ni Lẹkki, nipinlẹ Eko, logunjọ, oṣu kẹwaa, ọdun yii. Lasiko to n ba awọn oniroyin sọrọ lo sọ eleyii di mimọ. O ni iwadii ti n lọ lọwọ lati mọ awọn ti ... |
Wahala awọn Fulani darandaran yii le da ogun abẹle silẹ ni Naijiria O-Ṣoyinka | “Gbogbo wa o le sun ka kori sibi kan naa, ti gbogbo wa ba ni ka maa duro de ohun tijọba apapọ fẹẹ ṣe, niṣe la maa di ẹru nilẹ wa, iyẹn ta o ba ti i di ẹru ọhun bi mo ṣe n sọrọ yii. Ohun to n ṣẹlẹ lo mu ki Sunday Igboho gbe igbesẹ to gbe, ọrọ naa toju su u ni, o si pinnu lati ṣe nnkan kan nipa ẹ, ọna toun si mọ to le gb... |
Wọn ti yọ alaga kansu Onigbongbo bii ẹni yọ jiga, wọn lo kowo jẹ | Awọn kansẹlọ ijọba ibilẹ Onidagbasoke Onigbogbo, nipinlẹ Eko, ti fọwọ osi juwe ile fun alaga wọn, Ọnarebu Ọladọtun Ọlakanle, wọn leyi ti baba naa ko jẹ ninu owo kansu ọhun to gẹẹ. Gẹgẹ ba a ṣe gbọ, nibi ijokoo awọn aṣofin kansu naa to waye nirọlẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni Sẹkiteria Onigbongbo, ni iyọnipo naa ti waye. Ajọ... |
Ẹ sọ fun Akeredolu ko ma fi Amọtẹkun halẹ mọ wa o | Bi eto idibo ṣe n sunmọ etile, ọkan awọn eeyan kan ko balẹ mọ l’Ondo bayii, ohun to si n ka wọn laya ni bi gomina ipinlẹ naa ko ṣe ni fi ẹṣọ Amọtekun dunkooko mọ awọn ẹgbẹ alatako nibẹ. Ọkan ninu awọn ẹgbẹ oṣelu alatako ti sọrọ, iyen ẹgbẹ oṣelu Action Alliance, awọn gan-an ni wọn kọkọ pariwo sita pe Gomina Akeredolu ko... |
Ọwọ tẹ awọn akẹkọọ ileewe Akọka, ọbẹ ni wọn fi n gba mọto lọwọ awọn eeyan | Ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn gende meji ti wọn pe ara wọn lọmọleewe Federal College of Education (Technical) to wa l’Akọka, nipinlẹ Eko, Dare Williams, ẹni ọdun mẹtalelogun, Bethel Chukwuocha, ẹni ọdun mejidinlogun, ọkọ ayọkẹlẹ Toyota Corolla kan ni wọn fọbẹ gba lọwọ onimọto kọlọpaa too ri wọn mu. Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko,... |
Awọn araalu binu nitori b’ọlọpaa ṣe ti awọn OPC to mu Wakilu niluu Ayetẹ mọle | Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn eeyan n fi ibinu wọn han kaakiri ori ẹrọ ayelujara lori igbesẹ ti awọn ọlọpaa gbe pẹlu bi wọn ṣe ti mẹrin ninu awọn ọmọ ẹgbẹ OPC to lọọ mu ọkunrin Fulani to n da awọn eeyan Ibarapa, paapaa ju lọ ilu Ayetẹ laamu, iyẹn Iskilu Wakili. Awọn araalu ni iwa to ku diẹ kaato ni awọn agbofinro hu. ... |
Bím̀bọ́ Ọṣìn | Bím̀bọ́ Ọ̀ṣìn (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, oṣù Agẹmọ, ọdún 1971) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Oǹdó lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú pé wọ́n bí Bím̀bọ́ Ọ̀ṣìn lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1971 ni ìpínlẹ̀ Oǹdó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà , ó kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ Philosophy. Bím̀bọ́ Ọ̀ṣì... |
Ọrẹ Mohbad tawọn ọlọpaa n wa ti jọwọ ara rẹ fun wọn o | Ni bayii, awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti sọ pe gbajumọ olorin takasufee nni, Owodunni Ibrahim ẹni tawọn eeyan mọ si Primeboy tawọn ọlọpaa kede rẹ pe awọn n wa lori iku oloogbe Mohbad ti jọwọ ara rẹ silẹ fawọn tawọn si ti ju u sahaamọ awọn ni olu ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko. Wọn lawọn maa too foju rẹ bale-ẹjọ lopin... |
Ajagungbalẹ mẹta ko sọwọ ọlọpaa l’Odogbolu | Bi awọn ọkunrin yii ṣe ti wa ni ahamọ awọn ọlọpaa, lẹka itọpinpin, bẹẹ ni wọn ṣi n wa awọn yooku wọn ti wọn jọ ya wọ ori ilẹ kan ti iṣẹ ile ti n lọ lọwọ l’Odogbolu, nipinlẹ Ogun, iyẹn lọjọ kejidinlogun, oṣu kẹfa yii, nibi ti wọn ti le awọn to n ṣiṣẹ lori ilẹ naa danu, ti wọn si gba idaji miliọnu naira ati foonu ologoji... |
Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (11) | Ọgbọn buruku wa ninu awọn oyinbo. Gbogbo ohun ti Fulani ṣe fun wa, ati ohun ti wọn n ṣe lọwọlọwọ bayii fun wa, awọn oyinbo lo ta wa fun wọn. Ọgbọn buruku ni wọn lo fun wa. Bẹẹ ni ki i ṣe pe awọn baba wa yii ko kuku gbọn, wọn gbọn daadaa, awọn kan fi inu wenu lasan ni. Wọn ti ro pe bi awọn ti ri ni awọn Hausa wọnyi ri, ... |
Àjakálẹ̀-àrùn COVID-19 ní Bùrúndì | Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Burundi Àrùn Kòrónà wọ orílẹ̀-èdè Burundi ní ọjọ́ Kínní oṣù Kẹrin ọdún 2020. Ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kíní ọdún 2020, Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wíp... |
Wọn ti mu Johnson to n fi aṣọ ṣọja jale l’Ogudu | Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko lawọn ti fi pampẹ ofin gbe afurasi ọdaran kan, Johnson Godday, aṣọ ṣọja lo wọ sọrun, ṣugbọn a-lọ-kolohun-kigbe ẹda ni. Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, lọwọ ba jagunlabi naa ni nnkan bii aago mọkanla oru, nibi to ti ṣakọlu sawọn eeyan kan ti wọn n dari rele wọn lati ibiiṣẹ ounjẹ oojọ wọn. Bi Olumuyiwa ... |
O ma ṣe o, inu odo Ọyun ni ileeṣẹ panapana ti gbe oku ọkunrin yii jade | Ko sẹni to le ṣalaye ni pato bi oku gende kan ṣe denu odo Ọyun, nitosi ilu Ijagbo, nipinlẹ Kwara. Ṣadeede ni wọn ri i to le tente sori omi laaarọ Ọjọbọ Tọsidee, ọsẹ yii. Lai fi akoko ṣofo, ileeṣẹ panapana ni wọn ke pe lati waa gbe oku to ti mu omi yo ọhun jade, ko too di pe o bẹ, ti yoo si fa ajakale arun fun araalu to... |
Kín ni Yorùbá ń pè ní àpọ́n? | Àpọ́n ni ọmọ ọkùnrin tó́ ti tó ni ìyàwó ṣùgbọ́n tí kò ní ìyàwó. |
Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ní etí omi ní àwọn ìpínlẹ̀ yìí, ẹ tètè kó ẹrù yín o! | Àjọ tó ń mójútó ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, (NEMA) ti ṣèkìlọ̀ pé ó ṣeéṣe kí omíyalé àgbàrá ya ṣọ́ọ̀bù tún ṣọṣẹ́ gidigidi láìpẹ́ yìí nítorí bí orílẹ̀-èdè Cameroon ṣe fẹ́ ṣí omi odò Lagdo wọn sílẹ̀. NEMA ní àwọn ìpínlẹ̀ tó wà ní bèbè omi odò Benue àti River ní ó ṣeéṣe kí àgbàrá náà ṣe ìjàmbá fún jùlọ tí wọ́n... |
Ọwọ tẹ Ṣakiru, alaga kansu tẹlẹ to gbe egboogi oloro l’Ekoo | NDLEA, ajọ to n gbogun ti gbigbe egboogi oloro nilẹ wa (National Drug Law Enforcement Agency) sọ pe ọwọ awọn ti ba afurasi ọdaran kan to ti figba kan jẹ Igbakeji alaga kansu Lagos Island nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Aṣekun Kẹhinde Ṣakiru, wọn lọkunrin naa ni baba isalẹ fawọn arufin to n ṣowo egboogi oloro. Papakọ ofurufu Murita... |
Wọn ti ni kawọn kọsitọọmu da irẹsi ti wọn ko n’Ibadan pada kiakia | Ileegbimọ aṣofin agba ilẹ wa ti paṣẹ fawọn ileeṣẹ aṣọbode ilẹ wa, iyẹn awọn kọsitọọmu, pe ki wọn da awọn irẹsi atawọn ọja ọlọja ti wọn lọọ fọwọ agbara ko ninu ṣọọbu wọn n’Ibadan pada lai fakoko ṣofo, wọn niwa ti wọn hu naa ko bofin mu rara, aṣilo agbara ni. Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee yii, ni igbimọ alabẹ ṣekele lori ọrọ ilan... |
Ìjọba ìbílẹ̀ mélòó ni ó wà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun? | Ìjọba ìbílẹ̀ ọgbọ̀n ni. |
Wọn tun ti ri ile mi-in ti wọn ti n ṣe òwò ọmọ tita ni Mowe | Lẹyin ọjọ meji ti aṣiri ile ti wọn ti n ta awọn ọmọ ikoko tawọn ọmọbinrin ti ko ti i dagba ba bi ni Mowe tu, awọn ọlọpaa adugbo naa tun ti ri ile mi-in to jẹ owo ọmọ tita ni wọn n ṣe nibẹ ni Mowe kan naa. Opopona Lagos, Adesan, ni Mowe, ni ile ti wọn ti n fi awọn ọmọbinrin keekeeke ṣowo ibasun, ti wọn si n ta ọmọ ti wọ... |
Gbogbo agbara ti mo ni ni ma a lo lati jẹ ki Tinubu di aarẹ lọdun 2023- Olubadan | Olubadan tilẹ Ibadan, Ọba Saliu Adetunji, ti sọ pe bi igbin ba fa, ikarahun a tẹle e, lọrọ oun ati adari ẹgbẹ oṣelu APC, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu, bo ṣe n gbero lati dije dupo aarẹ orile-ede yii lọdun 2023. Ninu atẹjade kan to tọwọ alakooso-agba ikọ olupolongo fun Tinubu jade lọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu kẹfa, ọdun 2021, ... |
Aarẹ Trump ni ki Biden ma ti i dunnu o, ipade dile-ẹjọ | Lai ka ti bawọn eeyan ṣe n rọjo ikini ku oriire fun Ọgbẹni Joe Biden ti wọn ṣẹṣẹ kede rẹ bii Aarẹ tuntun fun orileede Amẹrika si, Aarẹ orileede naa, Donald Trump, ti ni ọrọ ibo yii ko ti i pari rara o, bẹẹ loun ko si reti ijo ọpẹ kan lẹsẹ Biden, tori lọsẹ ta a fẹẹ mu yii loun yoo gba kootu lọ lati pẹjọ lori ibo ti wọn ... |
O yẹ ki Aarẹ Buhari ko awọn igbimọ alaṣẹ rẹ wa ka jọ waa bẹ Yeye Ọṣun lori arun Korona ni- Ọṣunbiyii | Lati igba ti ayẹyẹ ọdun Ọṣun Oṣogbo to waye lopin ọsẹ to kọja ti ku ọjọ mẹta nijọba ipinlẹ Ọṣun, nipasẹ Kọmisanna fun ọrọ aṣa ati ibudo igbafẹ, Dokita Ọbawale Adebisi, ti kede pe ko ni i si aaye fun ipejọpọ gẹgẹ bo ṣe maa n waye lọdọọdun. Ọbawale sọ pe ko si aaye fun ayẹyẹ kankan latari bi iye awọn to n lugbadi arun Ko... |
Wọn ṣebura fun Akeredolu sipo gomina Ondo lẹẹkeji | Ẹsẹ o gbero ni gbọngan asa igbalode Doomu to wa loju ọna Igbatoro, l’Akurẹ, l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, lasiko ti wọn n ṣayẹyẹ ibura sipo gomina ẹlẹẹkeji fun Gomina Rotimi Akeredolu ati Igbakeji rẹ tuntun, Ọnarebu Lucky Aiyedatiwa. Nnkan bii aago mẹsan-an aarọ lawọn eeyan ti kun inu gbọngan ọhun bamubamu, ti wọn si n d... |
Nibi ija agba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun, eeyan marun-un ku, ọlọpaa ko mẹwaa ninu wọn n’Ilọrin | Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara, ti mu eeyan mẹwaa nibi ija agba laarin awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun meji, Ẹiyẹ ati Aiye, niluu Ilọrin, ti awọn marun-un si ti dero ọrun lẹnu ọjọ mẹta ti ija naa bẹrẹ. Ileesẹ ọlọpaa sọ fun ALAROYE pe ni bii, ọjọ mẹta sẹyin ti ija naa ti bẹrẹ laarin awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun mejeeji ọhun lawọn ti n gbe o... |
Nitori awọn ibeji Akeugbagold ti wọn ji gbe lọjọsi, ile-ẹjọ sọ awọn meje satimọle | Awọn mejeeje ti wọn fẹsun kan pe wọn lọwọ ninu bi wọn ṣe ji awọn ibeji Sheik Taofeeq Akeugbagold, gbe n’Ibadan ti dero ahamọ. Lọjọ Aje, Mọnde, l’Onidaajọ Emmanuel Idowu ti ile-ẹjọ Majisireeti to wa ni Iyaganku, n’Ibadan, paṣẹ ọhun nigba ti ọga agba awọn ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ, CP Joe Nwachukwu Enwonwu, gbe wọn lọ si kootu f... |
A fura pe Yinka yoo ku – Jacob Odumakin | Ọkan lara awọn ẹgbọn Oloogbe Yinka Odumakin, Pasitọ Jacob Odumakin, ti sọ pe asọtẹlẹ ti wa tẹlẹ lori iku to wọle wẹrẹ mu akikanju ọkunrin naa lọ lọjọ Abamẹta, o ni awọn si gbadura si i, ṣugbọn bo ṣe ṣẹlẹ ye Ọlọrun. Ninu ifọrọwerọ rẹ to ṣe pẹlu akọroyin ALAROYE nile awọn obi olóògbé naa to wa nìyi Mooro, nipinlẹ Ọṣun, o... |
Adajọ ti ju Adebọwale ọlọkada to fipa ba ọmọ ọdun mẹtala sun n’Ileefẹ sẹwọn | Ile-ẹjọ Majisreeti kan niluu Ileefẹ, ti ju Adebọwale Gboye, ẹni ọgbọn ọdun, sẹwọn lori ẹsun pe o fipa ba ọmọdebinrin ọmọ ọdun mẹtala lo po. Aago mẹrin irọlẹ ọjọ kẹrinlelogun, oṣu keje, ọdun yii, ni Adebọwale ki ọmọ naa mọlẹ lagbegbe Ọgbọn-Agbara, niluu Ileefẹ, to si ba a sun karakara. Agbefọba to n ṣe ẹjọ naa, Emmanuel... |
Ìjọba ìpínlẹ̀ mélòó ni ó wà ní gúsù-ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà? | Ìjọba ìpínlẹ̀ mẹ́fà ni. |
Abẹẹ ri Kalu, araale ẹ to n sun jeẹjẹ lo yinbọn mọ lẹgbẹẹ l’Abẹokuta | Ọlọrun nikan lo mọ ohun to faja to bẹẹ laarin ọkunrin ẹni ọdun marundinlogoji yii, Obinna Kalu, ati obinrin kan ti wọn jọ n gbele torukọ tiẹ n jẹ Adijat Balogun, to fi di pe maanu yii wọle tọ ọ nigba tiyẹn n sun oorun ọsan lọwọ lọjọ kẹrinla, oṣu kẹta yii, to si yinbọn mọ ọn lẹgbẹẹ otun nile wọn to wa ni Ilupeju /Sabo, ... |
Ṣẹgun to ṣẹṣẹ tẹwọn de ti tun fẹẹ pada sibẹ bayii o | Ọwọ awọn ọlọpaa ti tẹ ọkunrin kan ti wọn n pe ni Ṣẹgun nibi to ti n ji iṣu oniṣu wa ninu oko kan lagbegbe Fagun niluu Ondo. Gẹgẹ bi ohun t’ALAROYE gbọ, ọjọ pẹ ti ọkunrin ọmọ bibi Ire ni ipinlẹ Ọsun naa ti n ja awọn eeyan agbegbe ọhun lole ko too ṣe eyi tọwọ ti tẹ ẹ lọjọ Iṣẹgun, Tusidee ọsẹ yii. Obinrin araadugbo kan to... |
Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori Ẹgbẹ Akẹkọọ Poli Offa to fun awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun lami-ẹyẹ | Iwadii ti bẹrẹ bayii lori iroyin kan to gba ori ẹrọ ayelujara pe ẹgbẹ akẹkọọ, SUG, tileewe Poli Ọffa fun awọn ẹgbẹ okunkun ni ami-ẹyẹ laipẹ yii. Laarin ọsẹ yii ni aworan awọn ami-ẹyẹ naa ti wọn kọ orukọ awọn ẹgbẹ okunkun mẹta ọtọọtọ si lori gba ori ẹrọ ayelujara. Latigba naa lawọn eeyan si ti n sọ ọrọ buruku lu ẹgbẹ ak... |
Awọn ọmọ ẹgbẹ PDP fẹhonu han l’ Ọyọọ, wọn ni wọn fi tipa yan oludije le awọn lori | O fi han pe nnkan ko lọ deede ninu ẹgbẹ oṣelu People’s Democratic party, PDP ni ipinlẹ Ọyọ pẹlu bi awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu naa ṣe binu ya bo ọfiisi gomina ipinlẹ naa fún ifẹhonu han, wọn lawọn alagbara inu ẹgbẹ naa n fọwọ ọla gba awọn loju. Awọn olufẹhonu han ọhun ti wọn wa lati ijọba ibilẹ Ila-Oorun Ọyọ ni wọn fi aidunnu ... |
Awọn agbebọn ji Baalẹ Apanpa atiyawo rẹ gbe lọ labule kan n’Ibadan | Titi di ba a ṣe n sọ yii ni awọn ara abule ṣi n wa Baale Ararọmi, Alaaji Tafa Apanpa, atiyawo rẹ ti awọn agbebọn ji lọ ni oru ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ni abule kan to wa ni agbegbe Bakatari, nijọba ibilẹ Ido, niluu Ibadan, nipinlẹ Ọyọ. Gẹgẹ bi Ajọ Akoroyinjọ ilẹ wa (NAN), to gbọ nipa iṣẹlẹ naa ṣe sọ, lasiko arọọda... |
Awọn agbebọn tun ya wọ ileewe kan ni Kaduna, wọn ko ọpọlọpọ akẹkọọ lọ | Ni nnkan bii aago kan oru ni awọn janduku agbebọn kan tun ya wọ ileewe girama kan ti wọn n pe ni Bethel Secondary School, nijọba ibilẹ Chikun, nipinlẹ Kaduna, ti wọn si ko ọpọlọpọ awọn akẹkọọ ti ko sẹni to ti i le sọ iye wọn lọ. A gbọ pe ṣe ni wọn ya wọ inu ọgba ileewe naa, ti wọn si bẹrẹ si i yinbọn leralera lati dẹru... |
Kí ni orúkọ àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tí ó wà ní ìpínlè Ábíá? | Àwọn ni: Abá North (Abá Àríwá), Abá South (Abá Gúsù), Arochukwu, Bende, Ikwuano, Isiala Ngwa North (Isiala Ngwa Àríwá), Isiala Ngwa South (Isiala Ngwa Gúsù), Isuikwuato, Obi Ngwa, Ohafia, Osisioma, Ngwa, Ugwunagbo, Ukwa East (Ukwa Ìlà Oòrùn), Ukwa West (Ukwa Ìwọ̀ Oòrùn), Umuahia North (Umuahia Àríwá), Umuahia South (Um... |
Barbara Soky | Barbara Soky (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Bara Sokoroma ) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti akọrin tẹ́lẹ̀rí tí ó di gbajúmọ̀ lẹ́hìn kíkópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Mirror in the Sun. Ó sinmi iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lẹ́hìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ipa ní àwọn ọdún 80 àti 90, kí ó tó padà sí ní bá iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ lọ nísẹ̀yín. ... |
Wasiu Ayinde bẹ ẹgbẹ FIBAN, o loun ko ni i ṣeru ẹ mọ | Laafin Olu Itori nipade ọhun ti waye l’Ọjọ̣bọ, Tọsidee, ọsẹ yii, nibi ti wọn ti yanju wahala to wa laarin Oluaye Fuji, Alhaji Wasiu Ayinde, atawọn ẹgbẹ sọrọsọrọ, eyi to ti n ja ran-in-ran-in nilẹ lati bii ọjọ melooo kan sẹyin. Nibi ipade ọhun ni Wasiu Ayinde ti bẹ awọn sọrọsọrọ yii, to si fi da wọn loju pe irufẹ iwa bu... |
O ti doju ẹ bayii o: ‘YORUBA GBỌDỌ FI NAIJIRIA SILẸ DANDAN!’ | Awọn ọmọ Yoruba yoo kuro lara Naijiria, kinni naa ko si ni i pẹ rara. Awọn agbaagba Yoruba ni wọn n sọ bẹẹ, bẹẹ ni ki i ṣe ẹni kan ninu wọn, ki i ṣe ẹni meji tabi mẹta. Ohun kan naa ni wọn n tẹnu mọ, iyẹn naa ni irẹjẹ ati awọn iwa buruku mi-in ti wọn n hu si Yoruba ni Naijiria, eyi to si le ju lẹnu ọjọ mẹta yii ni ti a... |
Ajọ eleto idibo pariwo: Bi wọn ṣe n kọ lu awọn ileeṣẹ wa yii yoo ṣakoba feto idibo to n bọ o | “Laarin ọsẹ mẹta pere ọfiisi ileeṣẹ wa meje ni wọn kọ lu. Wọn dana sun marun-un, wọn si jalẹkun, wọn si ṣe ibẹ baṣubaṣu. Ipinlẹ Abia, Akwa Ibom, Enugu ati Ebonyi lawọn iṣẹlẹ naa ti waye. A o mọ ero ọkan awọn ti wọn wa nidii akọlu wọnyi to fi jẹ ileeṣẹ INEC ni wọn doju sọ lasiko yii. Ṣugbọn ohun to daju ni pe ti iwa bas... |
Ijọba bẹrẹ iwadii lori ọkọ BRT to gbina lọna Ikorodu | Ere asadigbolura-ẹni ati akọlukọgba gidi lo waye lọsan-an ọjọ Aje, Mọnde yii, pẹlu bawọn ero ọkọ ijọba BRT kan ṣe gbina lori irin n’Ikorodu, nipinlẹ Eko. Ọgbẹni Ibrahim Farinloye, ọga agba ajọ ijọba apapọ to n ri si ọrọ pajawiri, ẹkun ti Guusu/Iwọ-Oorun fidi iṣẹlẹ yii mulẹ, o ni ero marundinlaaadọta lo wa ninu ọkọ naa ... |
Ijọba apapọ da ile-ẹkọ poli silẹ nipinlẹ Ọyọ | Ààrẹ orile-ede yii, Ọgagun Muhammadu Buhari, ti fọwọ si idasilẹ ile-ẹkọ gbogboniṣe si ipinlẹ Ọyọ. Akọwe agba nileeṣẹ to n mokuto eto ẹkọ labẹ ijọba apapọ orileede yii, Ọgbẹni sonny S.T. Echono, lo fìdí iroyin yii múlẹ nínú lẹta to fi kede igbesẹ naa fún Ẹnjinnia Ṣẹyin Makinde ti i ṣe gomina ipinlẹ Ọyọ. Ilu Ayédé, la gb... |
Awọn ti wọn n faṣọ ṣọja jale n’Ijẹbu-Ifẹ ree o | Ṣe ẹ ranti awọn ayederu ṣọja to wọ aṣọ ologun, ti wọn si n da awọn eeyan lọna nibẹrẹ oṣu yii, lagbegbe Ijẹbu -Ifẹ, nipinlẹ Ogun, eyi tawọn ọlọpaa pa ọkan ninu wọn, ọwọ SARS ti tẹ awọn yooku bayii. Ikechukwu Alore, Ifeanyi Emmanuel, Chibueze Kingsley, Obiora Micheal, Elias John, Vincent Magnus ati Chigozie Micheal lawọn... |
Eeyan keeyan l’Elisha yii o, ọmọ ọdun mẹrin lo fipa ba lo pọ ni Warewa | Ọwọ ṣinkun ọlọpaa ti tẹ ọkunrin kan, Elisha James, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn (25), to gbe ọmọbinrin ọmọ ọdun mẹrin wọ yara, nile wọn to wa ni Warewa, nijọba ibilẹ Ifọ, to si fipa ba a lo pọ gidigidi. Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu kẹta, ọdun 2021 yii, ni Elisha huwa ọhun. Iya ọmọdebinrin naa ṣalaye fawọn ọlọpaa ni t... |
Nitori ija Ṣaṣa, awọn Hausa ko ko ounjẹ wọ Ibadan mọ o | Ohun eelo ọbẹ̀ bíi ata, tòmáàtì, àlùbọ́sà, titi dori ẹran námọ̀ ati ẹ̀wà ti di ọ̀wọ́n gógó n’Ibadan ati kaakiri ipinlẹ Ọyọ bayii nitori bi awọn Hausa ti wọn n pese awọn nnkan wọnyi ṣe pinnu pé àwọn kò ní í ko ounjẹ wọlu Ibadan mọ. Ìpinnu awọn Hausa yii kò ṣẹ̀yìn ija to waye laarin Yoruba atawọn Hausa lẹyin ti Hausa alá... |
Nitori bawọn Hausa ṣe dawọ kiko ounjẹ wa silẹ Yoruba duro, awọn kọmiṣanna eto ọgbin nipinlẹ Yoruba ṣepade | Awọn kọmiṣanna fun eto ọgbin lawọn ipinlẹ mẹfẹẹfa nilẹ Yoruba, Ọyọ, Ondo, Ekiti, Ogun, Ọṣun ati Eko n ṣe ipade pajawiri kan lọwọlọwọ bayii lori ẹrọ ayelujara. Lara awọn ti wọn darapọ mọ ipade yii pẹlu wọn ni ileeṣẹ eto ọgbin nilẹ Yoruba, ‘South WestAgricultural Company’ (SWACO). Bakan naa ni ileeṣẹ to wa fun idagbasoke... |
Wo ǹkan méje tó yẹ kí o mọ̀ nípa Primeboy, ọ̀rẹ́ Mohbad tó wà ní àhámọ́ ọlọ́pàá | Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko kede l'Ọjọru pe awọn n wa Owodunni Ibrahim ti ọpọ mọ si Primeboy lẹyin to kọ lati yọju fun ifọrọwanilẹnuwo lori iku ọdọmọde olorin, Ilerioluwa Aloba, Mohbad. Primeboy ti ọpọ mi ni ọrẹ timọtimọ Mohbad ni kọmiṣọnna ọlọpaa ipinlẹ Eko, Idowu Owohuwa ninu atẹjade ti SP Benhamin Hundeyin fi sita sọ p... |
Ọpẹ o! Ajeji ti wọn ji gbe n’Ibadan ti bọ lọwọ awọn ajinigbe | Lẹyin bii ogun wakati ti wọn ji ara ilẹ Lebanon kan, Ọgbẹni Hassan Mills gbe, ọkunrin naa ti ri ìdáǹdè gba, o si ti dara pọ mọ awọn ẹbi atawọn oṣiṣẹ ileeṣẹ ẹ ba a ṣe n kọroyin yii. Ọgbẹni Mills, ẹni to ni oko nla kan ti wọn n pe ni Panorama Farm, laduugbo Mẹkun, nitosi Oke-Alaro, n’Ibadan, lawọn giripa agbebọn kan lọọ ... |
Abel Ìdòwú Ọláyínká | Abẹli Idowu Ọlayinka FAS (ti a bi ní ọjọ́ kẹrìndínlógún, oṣù Èrèlé, ọdún 1958) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọ̀jọ̀gbọ́n applied geophysics. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ igbákejì Gíwá àti Gíwá Yunifásítì Ìbàdàn. Bákan náà ni ó jẹ́ Ààrẹ Ẹgbẹ́ Ìṣàkóso Ìwádìí àti ọ̀tun-ìmọ apá, Ìwọ̀ - Oòrùn Áfíríkà. Ní 2012, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí ọ... |
Lẹyin ọdun kan to ti sa lọ, afurasi to da wahala silẹ niluu Odo-Ọwa dero ahamọ | Lẹyin ọdun kan ati oṣu mẹrin ti wọn lo ti sa lọ, ọwọ ọlọpaa pada tẹ Akinọla Babatunde, ọkan lara awọn afurasi to da ilu Odo-Ọwa atawọn ilu to wa lagbegbe rẹ ru, nibi ti eeyan mẹta ti padanu ẹmi wọn, o si ti dero ahaamọ bayii. Akinọla tawọn eeyan mọ si Agoro lawọn ọlọpaa wọ wa sile-ẹjọ Magisreeti kan niluu Ilọrin l’Ọjọb... |
Ẹ̀yà àrà wò ni o wà fún ìríran? | Ojú |
L’Ekiti wọn gbe ọmọ tuntun jojolo sinu ile akọku | Kayeefi nla lo jẹ fun gbogbo awọn eeyan to wa adugbo Moferere, niluu Ado-Ekiti, pẹlu bi wọn ṣe ṣadeede ba ọmọ tuntun jojolo kan ninu ile akọku kan ni ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii. Niṣe ni wọn ba ikoko ọhun nibi to ti n ju apa ati ẹsẹ, lori ọra dudu kan ti wọn tẹ ẹ si pẹlu iwọ ati ibi ọmọ naa ninu agbara ẹjẹ. Awọn araad... |
Àsìkò wo ni a máa ń se eré ìdárayá? | Lẹ́yìn iṣẹ́ òòjọ́ ni. |
Mamarumo marokane | Mamarumo Marokane (bí ní. 1997) jẹ́ Òṣèré àti Òlùṣètò South African. Wọ́n mọ̀ ọ́ fún ìfarahàn rẹ̀ ní Shadow and MTV Shuga. Wọ́n bí Marokane ní ọdún 1996 láìmọ̀ àsìkò gan-an. Ó kàwé ní CityVarsity School of Media and Creative Arts. Ó lè sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Sepedi àti èdè Setswana. Lọ́wọ́ ó ṣe Vuvu lórí àbùkù pẹ̀lú àwọn ... |
Àmì ẹ̀yẹ góòlù Olympic mélòó ni Usain Bolt ní lápapọ̀? | Àmì ẹ̀yẹ góòlù mẹ́jọ ni. |
Ipo adari ilu di wahala n’Ileṣha-Baruba, ọpọlọpọ eeyan lo fara pa | Ija nla kan bẹ silẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, lagbegbe Gukonbu/Kpakotoru, niluu Ilesha-Baruba, nijọba ibilẹ Baruten, nipinlẹ Kwara, nitori iyansipo Alhaji Audi Ba’ase (Abiyeruma tilu Ilesha) gẹgẹ bii olori agbegbe Gukonbu/Kpakotoru. Agbegbe Moshi-Gbofan, niluu Yashikira, nijọba ibilẹ Baruten. ALAROYE gbọ pe Ọba ilu Il... |
Ọmọkunrin yii gun lanlọọdu ẹ pa nitori obinrin | Njẹ ẹyin gbọ nipa ọmọkunrin ẹni ọdun mọkanlelogun kan to gun lanlọọdu ẹ pa lọsẹ to kọja yii nipinlẹ Anambra? Bẹẹ, amọran lasan ni baba onile rẹ yii gba a, o ni ko yee ko obinrin oriṣiiriṣii wale. Ohun to bi ayalegbe torukọ ẹ n jẹ Onyemachi Mmaju ninu niyẹn to fi gun lanlọọdu ẹ torukọ iyẹn n jẹ Umeadi Oyiboka, pa. Aluko... |
Kootu Agbaaye gba iwe ifiyajẹni ti Akintoye, Igboho kọ si wọn wọle | Ikọlu tawọn DSS to n ṣiṣẹ fun Aarẹ Muhammadu Buhari ṣe sile Sunday Igboho lọjọ kin-in-ni, oṣu keje yii, ti de etiigbọ kootu ilẹ okeere to n gbọ ẹsun ọdaran bayii ni Rome, iyẹn International Criminal Court, wọn si ti lawọn yoo ṣiṣẹ le e lori bo ṣe yẹ. Ọjọ Iṣẹgun, ọjọ kẹtala, oṣu keje yii, ni kootu naa sọ ọ di mimọ pe aw... |
Lẹyin ti Taoreed gbowo ni banki, wọn yinbọn pa a, wọn tun gbe owo ẹ sa lọ n’Ibadan | Ẹkun lawọn ti ko le mu iṣẹlẹ naa mọra bu si nigba ti wọn ri oku ọkunrin kan, Taoreed Oluṣọla, nilẹẹlẹ lẹyin ti awọn adigunjale yinbọn pa a ti wọn si ja a lole owo to ṣẹṣẹ gba ni banki. Ni nnkan bii aago kan aabọ ọsan ana, Mọnde, ọjọ Aje niṣẹlẹ ọhun waye nitosi sẹkiteriati ijọba ipinlẹ Ọyọ to wa laduugbo Agodi n’Ibadan.... |
Fausat Balógun | Fausat Balogun tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Madam ṣajẹ, ní wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì ọdún 1959 (February 13th, 1959) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá ni Madam ṣajẹ tí gbajúmọ̀. Gbajúmọ̀ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá àgbéléwò bẹ̀rẹ̀ nígbà tí ó kópa ère àwàdà lorí tẹlifíṣàn ... |
Iya n jẹ wa pupọ lorileede yii, ẹ jẹ ka gbogun ti iwa ijẹgaba awọn Fulani-Ayọ Adebanjọ | Adari ẹgbẹ Afẹnifẹre lorileede yii, Oloye Ayọ Adebanjọ, ti sọ pe ki ẹnikẹni ma ṣe gbiyanju lati yi ọrọ to n lọ lọwọ lorileede yii pada rara nipasẹ ibanilorukọ jẹ, ṣugbọn ki wọn sọ fun ijọba lati gbe igbesẹ to tọ. Oloye Adebanjọ, ẹni to sọrọ naa nibi eto isinku ti wọn ṣe fun alukoro ẹgbẹ naa, Yinka Odumakin, eyi to waye... |
Yusuf Maart | Moegamat Yusuf Maart (ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu Keje odun 1995) jẹ agbabọọlu South Africa ti o n gba iwaju fun ẹgbẹ South Africa Premier Division Sekhukhune United ati ẹgbẹ orilẹ-ede South Africa . Maart ni a bi ni Cape Town, o si dagba ni Atlantis . Orlando Pirates ṣe akiyesi rẹ ni ọdun 2016 lẹhin ti won yan Gẹg... |
Awọn ọlọdẹ yari l’Ọṣun, wọn lawọn o ba Amọtẹkun ṣiṣẹ papọ mọ | Agbarijọpọ ẹgbẹ awọn ọlọdẹ nipinlẹ Ọṣun, (Hunters Group of Nigeria, Osun State Chapter) ti kede pe kaka ki ekute ẹṣọ Amọtẹkun ṣe akapo ẹkun awọn, ki onikaluuku rọra ṣe ọdẹ rẹ lọtọọtọ latari iyanjẹ ọlọkan-o-jọkan ti oju awọn ti ri. Alakooso ẹgbẹ naa l’Ọṣun, Nurein Hammed, lo sọrọ yii fawọn oniroyin niluu Oṣogbo l’Ọjọbọ,... |
Ileeṣẹ ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori oku Kabiru ti wọn ba lorita Ọkinni, nipinlẹ Ọṣun | Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun, SP Yẹmisi Ọpalọla, ti sọ pe iwadii ti bẹrẹ lori iku ọmọkunrin kan ti awọn eeyan ilu Ọkinni, nijọba ibilẹ Ẹgbẹdọrẹ, ba lorita ilu naa nidaaji ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii. Ṣe lawọn araalu deede ba oku ọkunrin ti wọn pe ni Kabiru naa ninu agbara ẹjẹ, ti ko si sẹni to mọ bo ṣe debẹ tabi ... |
Okokomaiko | Okokomaiko jẹ agbegbe kan ni ilu Ojo, ti o wa ni Ipinle Eko, guusu iwọ-oorun Naijiria, lẹba opopona Eko si Badagry. Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó, lábẹ́ ìdarí Gómìnà tẹ́lẹ̀ rí Akinwunmi Ambode so pàtàkì ọ̀nà yìí ní ẹkùn ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Áfíríkà, wọ́n sì ti pinnu láti gbòòrò sí òpópónà Èkó sí Badagry sí òpópónà mẹ́wàá. Ilé yii bẹrẹ ... |
Korona wọ ọsibitu jẹnẹra ni Ṣagamu, ogun oṣiṣẹ lo ti mu | Bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, o kere tan, ogun eeyan ninu awọn oṣiṣẹ ileewosan jẹnẹra ti ipinlẹ Ogun to wa ni Ṣagamu, iyẹn Ọlabisi Ọnabanjọ(OOUTH), lo ti ni arun Korona, gẹge ba a ṣe gbọ. Ẹka awọn to n gba ẹjẹ awọn eeyan fun ayẹwo ni arun yii ti ṣẹyọ, bẹẹ ni wọn ni ẹnikan ninu awọn ogun eeyan to ti ni Korona yii tilẹ ti ko ... |
Lagos Black Heritage Festival | Lagos Black Heritage Festival (LBHF) jẹ iṣẹlẹ ọdọọdun ni Ipinle Eko ti o tun pẹlu Eko Carnival . Ayẹyẹ naa jẹ ajọdun ti aṣa ati itan-akọọlẹ ti o pinnu lati ṣe afihan ọlọrọ ati oniruuru ohun-ini ile Afirika. LBHF ṣe ayẹyẹ àtinúdá ilẹ̀ Áfíríkà pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ oríṣiríṣi bíi ijó ìbílẹ̀ àti ti ìgbàlódé, eré, orin, kíkún, àt... |
Nitori kanifa, awọn janduku ba ọpọlọpọ dukia jẹ l’Adewọle, n’Ilọrin | Bo tilẹ jẹ pe ọwọ ti tẹ diẹ lara awọn janduku kan to da wahala silẹ laduugbo Adewọle, niluu Ilọrin, laaarọ ọjọ Aje, Mọnde, nitori bawọn agbofinro ko ṣe gba awọn ọdọ laaye lati ṣe ayẹyẹ kanifa, sibẹ inu ibẹru lawọn araadugbo naa ṣi n gbe. ALAROYE gbọ pe ilu Eko ni ọpọlọpọ awọn bọọsi to sọ ara wọn di janduku yii ti wa, k... |
Ẹ ṣofin kawọn lanlọọdu yee gbowo ile lọdọọdun, oṣooṣu ti daa – Faṣọla | Minisita feto iṣẹ ode ati ọrọ ile gbigbe nilẹ wa, Amofin Babatunde Raji Faṣọla, ti gba gbogbo awọn gomina ipinlẹ kaakiri orileede yii lamọran pataki, o ni ki kaluku wọn lọọ ṣofin lawọn ipinlẹ wọn, oṣooṣu lo daa kawọn lanlọọdu maa gbowo ile, eyi lo si le din inira tawọn ayalegbe n koju ku. Faṣọla sọrọ yii nibi ipade ape... |
Awọn Fulani to sa kuro n’Igangan ya wọ Igbẹti, lawọn araalu ba dawo ọkọ fun wọn pe ki wọn maa lọ | Ko din laaadọrin (70) awọn Fulani darandaran ti wọn sa kuro n’Igangan, nijọba ibilẹ Ila-Oorun Ibarapa, lẹyin ikọlu ti wọn ṣe sawọn araalu naa ti wọn tun sa wọ Igbẹti, nipinlẹ Ọyọ lọjọ Ẹti to kọja yii ti i ṣe ọjọ kọkanla, oṣu kẹfa. Ṣugbọn awọn araalu naa ko gba wọn laaye, niṣe ni wọn dawo ọkọ fun wọn pe ki wọn maa lọ. G... |
Ìjọba ìbílẹ̀ mélòó ni ó wà ní ìpínlẹ̀ Borno? | Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ní. |
Adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Gbenga Aluko l’Ekiti | Ile-ẹjọ giga kan nipinlẹ Ekiti, to filu Ado-Ekiti ṣebujokoo ti ni ki wọn lọọ yẹgi fun Gbenga Aluko, ẹni tawọn eeyan tun mọ si Cherry, titi ti ẹmi yoo fi bọ lara ẹ. Adajọ ni ọkunrin ẹni ọdun mọkandinlọgbọn ti ọwọ tẹ yii jẹbi ẹsun iku gẹgẹ bi ofin ipinlẹ Ekiti ṣe la a kalẹ nitori to dara pọ mọ ẹgbẹ okunkun. Wọn ni lọjọ k... |
Adajọ ni ki wọn yẹgi fun Ọlajide titi ẹmi yoo fi bọ lara rẹ | Ile-ẹjọ giga ti ipinlẹ Ekiti, to wa l’Ado-Ekiti, ti paṣẹ pe ki wọn so ọmọ ọdun mejilelogun kan, Kẹhinde Ọlajide, rọ titi ti ẹmi yoo fi bọ lara rẹ. Bakan naa nile-ẹjọ yii tun paṣẹ pe ki awọn mẹta mi-in Kareem Azeez, ẹni ọdun mẹrinlelogun, Bamisile Lateef, ẹni ọdun mejidinlọgbọn ati Adebayọ Baṣiru, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn, t... |
Bi Kinsley ṣe fẹẹ wọn ṣọọṣi ni Festac lawọn agbebọn ji i gbe lọ l’Ekoo | Awọn afurasi ajinigbe mẹta kan ti ji Ọgbẹni Kinsley Ogbuagu gbe lẹnu ọna ṣọọṣi to ti fẹẹ lọọ jọsin lọjọ Aiku, Sannde yii, ko si ti i sẹni to mọ ibi tọkunrin naa ha si di ba a ṣe n sọ yii. Ba a ṣe gbọ, ni nnkan bii aago mẹfa aabọ owurọ ni ọkunrin naa de ileejọsin Catholic Church of the Visitation, to wa lagbegbe Festac,... |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.